Ìṣe 10:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Ẹnu ya àwọn onígbàgbọ́* tó ti dádọ̀dọ́* tí wọ́n bá Pétérù wá, torí pé ẹ̀bùn ọ̀fẹ́ ẹ̀mí mímọ́ tú jáde sórí àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè pẹ̀lú. Gálátíà 2:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Torí kí àwọn kan látọ̀dọ̀ Jémíìsì+ tó dé, ó máa ń bá àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè jẹun;+ àmọ́ nígbà tí wọ́n dé, kò ṣe bẹ́ẹ̀ mọ́, ó sì ya ara rẹ̀ sọ́tọ̀, torí ó ń bẹ̀rù àwọn tó dádọ̀dọ́.*+
45 Ẹnu ya àwọn onígbàgbọ́* tó ti dádọ̀dọ́* tí wọ́n bá Pétérù wá, torí pé ẹ̀bùn ọ̀fẹ́ ẹ̀mí mímọ́ tú jáde sórí àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè pẹ̀lú.
12 Torí kí àwọn kan látọ̀dọ̀ Jémíìsì+ tó dé, ó máa ń bá àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè jẹun;+ àmọ́ nígbà tí wọ́n dé, kò ṣe bẹ́ẹ̀ mọ́, ó sì ya ara rẹ̀ sọ́tọ̀, torí ó ń bẹ̀rù àwọn tó dádọ̀dọ́.*+