1 Sámúẹ́lì 8:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nígbà tó yá, gbogbo àgbààgbà Ísírẹ́lì kóra jọ, wọ́n sì wá sọ́dọ̀ Sámúẹ́lì ní Rámà. 5 Wọ́n sọ fún un pé: “Wò ó! O ti darúgbó, ṣùgbọ́n àwọn ọmọ rẹ kò tẹ̀ lé àpẹẹrẹ rẹ. Ní báyìí, yan ọba fún wa tí á máa ṣe ìdájọ́ wa bíi ti gbogbo orílẹ̀-èdè yòókù.”+
4 Nígbà tó yá, gbogbo àgbààgbà Ísírẹ́lì kóra jọ, wọ́n sì wá sọ́dọ̀ Sámúẹ́lì ní Rámà. 5 Wọ́n sọ fún un pé: “Wò ó! O ti darúgbó, ṣùgbọ́n àwọn ọmọ rẹ kò tẹ̀ lé àpẹẹrẹ rẹ. Ní báyìí, yan ọba fún wa tí á máa ṣe ìdájọ́ wa bíi ti gbogbo orílẹ̀-èdè yòókù.”+