-
1 Sámúẹ́lì 10:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Lẹ́yìn náà, ó ní kí ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì sún mọ́ tòsí ní ìdílé-ìdílé, a sì mú ìdílé àwọn Mátírì. Níkẹyìn, a mú Sọ́ọ̀lù ọmọ Kíṣì.+ Àmọ́ nígbà tí wọ́n wá a lọ, wọn ò rí i.
-