Hábákúkù 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 “Ẹ wo àwọn orílẹ̀-èdè kí ẹ sì kíyè sí i! Kí ẹnu yà yín bí ẹ ṣe ń wò wọ́n, kí ó sì jọ yín lójú;Torí ohun kan máa ṣẹlẹ̀ lásìkò yín,Tí ẹ ò ní gbà gbọ́ tí wọ́n bá tiẹ̀ sọ ọ́ fún yín.+
5 “Ẹ wo àwọn orílẹ̀-èdè kí ẹ sì kíyè sí i! Kí ẹnu yà yín bí ẹ ṣe ń wò wọ́n, kí ó sì jọ yín lójú;Torí ohun kan máa ṣẹlẹ̀ lásìkò yín,Tí ẹ ò ní gbà gbọ́ tí wọ́n bá tiẹ̀ sọ ọ́ fún yín.+