Ìṣe 1:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Nígbà tí wọ́n dé, wọ́n lọ sínú yàrá òkè tí wọ́n ń gbé. Àwọn ni: Pétérù pẹ̀lú Jòhánù àti Jémíìsì àti Áńdérù, Fílípì àti Tọ́másì, Bátólómíù àti Mátíù, Jémíìsì ọmọ Áfíọ́sì àti Símónì onítara pẹ̀lú Júdásì ọmọ Jémíìsì.+
13 Nígbà tí wọ́n dé, wọ́n lọ sínú yàrá òkè tí wọ́n ń gbé. Àwọn ni: Pétérù pẹ̀lú Jòhánù àti Jémíìsì àti Áńdérù, Fílípì àti Tọ́másì, Bátólómíù àti Mátíù, Jémíìsì ọmọ Áfíọ́sì àti Símónì onítara pẹ̀lú Júdásì ọmọ Jémíìsì.+