Ìṣe 13:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Bí wọ́n ṣe ń ṣiṣẹ́ Jèhófà,* tí wọ́n sì ń gbààwẹ̀, ẹ̀mí mímọ́ sọ pé: “Ẹ ya Bánábà àti Sọ́ọ̀lù+ sọ́tọ̀ fún mi kí wọ́n lè ṣe iṣẹ́ tí mo pè wọ́n sí.”+ 3 Lẹ́yìn tí wọ́n gbààwẹ̀, tí wọ́n sì gbàdúrà, wọ́n gbé ọwọ́ lé wọn, wọ́n sì rán wọn lọ.
2 Bí wọ́n ṣe ń ṣiṣẹ́ Jèhófà,* tí wọ́n sì ń gbààwẹ̀, ẹ̀mí mímọ́ sọ pé: “Ẹ ya Bánábà àti Sọ́ọ̀lù+ sọ́tọ̀ fún mi kí wọ́n lè ṣe iṣẹ́ tí mo pè wọ́n sí.”+ 3 Lẹ́yìn tí wọ́n gbààwẹ̀, tí wọ́n sì gbàdúrà, wọ́n gbé ọwọ́ lé wọn, wọ́n sì rán wọn lọ.