Ìṣe 18:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Lẹ́yìn tó lo àkókò díẹ̀ níbẹ̀, ó kúrò, ó sì ń lọ láti ibì kan sí ibòmíì ní ilẹ̀ Gálátíà àti Fíríjíà,+ ó ń fún gbogbo ọmọ ẹ̀yìn lókun.+
23 Lẹ́yìn tó lo àkókò díẹ̀ níbẹ̀, ó kúrò, ó sì ń lọ láti ibì kan sí ibòmíì ní ilẹ̀ Gálátíà àti Fíríjíà,+ ó ń fún gbogbo ọmọ ẹ̀yìn lókun.+