2 Kọ́ríńtì 11:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Yàtọ̀ sí àwọn nǹkan tó jẹ́ ti òde yìí, nǹkan míì tún wà tó ń rọ́ lù mí láti ọjọ́ dé ọjọ́:* àníyàn lórí gbogbo ìjọ.+
28 Yàtọ̀ sí àwọn nǹkan tó jẹ́ ti òde yìí, nǹkan míì tún wà tó ń rọ́ lù mí láti ọjọ́ dé ọjọ́:* àníyàn lórí gbogbo ìjọ.+