Ìṣe 13:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Nígbà náà, Pọ́ọ̀lù àti àwọn alábàákẹ́gbẹ́ rẹ̀ wọ ọkọ̀ òkun láti Páfò, wọ́n sì dé Pẹ́gà ní Panfílíà. Àmọ́ Jòhánù+ fi wọ́n sílẹ̀, ó sì pa dà sí Jerúsálẹ́mù.+
13 Nígbà náà, Pọ́ọ̀lù àti àwọn alábàákẹ́gbẹ́ rẹ̀ wọ ọkọ̀ òkun láti Páfò, wọ́n sì dé Pẹ́gà ní Panfílíà. Àmọ́ Jòhánù+ fi wọ́n sílẹ̀, ó sì pa dà sí Jerúsálẹ́mù.+