Ìṣe 16:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ó mú wọn lọ ní òru yẹn, ó sì wẹ ojú ọgbẹ́ wọn. Lẹ́yìn náà, òun àti gbogbo agbo ilé rẹ̀ ṣèrìbọmi láìjáfara.+ Ìṣe 18:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àmọ́ Kírípọ́sì,+ alága sínágọ́gù, di onígbàgbọ́ nínú Olúwa, òun pẹ̀lú gbogbo agbo ilé rẹ̀. Ọ̀pọ̀ àwọn ará Kọ́ríńtì tí wọ́n gbọ́ bẹ̀rẹ̀ sí í gbà gbọ́, wọ́n sì ṣèrìbọmi.
33 Ó mú wọn lọ ní òru yẹn, ó sì wẹ ojú ọgbẹ́ wọn. Lẹ́yìn náà, òun àti gbogbo agbo ilé rẹ̀ ṣèrìbọmi láìjáfara.+
8 Àmọ́ Kírípọ́sì,+ alága sínágọ́gù, di onígbàgbọ́ nínú Olúwa, òun pẹ̀lú gbogbo agbo ilé rẹ̀. Ọ̀pọ̀ àwọn ará Kọ́ríńtì tí wọ́n gbọ́ bẹ̀rẹ̀ sí í gbà gbọ́, wọ́n sì ṣèrìbọmi.