Ìṣe 22:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Àmọ́ nígbà tí wọ́n ti na Pọ́ọ̀lù tàntàn láti nà án lẹ́gba, ó sọ fún ọ̀gá ọmọ ogun tó dúró níbẹ̀ pé: “Ṣé ó bófin mu fún yín láti na ará Róòmù* tí wọn ò tíì dá lẹ́bi lẹ́gba?”*+ Ìṣe 23:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Àwọn Júù mú ọkùnrin yìí, wọ́n sì ti fẹ́ pa á, àmọ́ mo tètè wá pẹ̀lú àwọn ọmọ ogun mi, mo sì gbà á sílẹ̀,+ torí mo gbọ́ pé ará Róòmù ni.+
25 Àmọ́ nígbà tí wọ́n ti na Pọ́ọ̀lù tàntàn láti nà án lẹ́gba, ó sọ fún ọ̀gá ọmọ ogun tó dúró níbẹ̀ pé: “Ṣé ó bófin mu fún yín láti na ará Róòmù* tí wọn ò tíì dá lẹ́bi lẹ́gba?”*+
27 Àwọn Júù mú ọkùnrin yìí, wọ́n sì ti fẹ́ pa á, àmọ́ mo tètè wá pẹ̀lú àwọn ọmọ ogun mi, mo sì gbà á sílẹ̀,+ torí mo gbọ́ pé ará Róòmù ni.+