17 Ìdí nìyí tí Baba fi nífẹ̀ẹ́ mi,+ torí pé mo fi ẹ̀mí mi lélẹ̀,+ kí n lè tún rí i gbà. 18 Kò sí èèyàn kankan tó gbà á lọ́wọ́ mi, èmi ni mo yọ̀ǹda láti fi lélẹ̀. Mo ní àṣẹ láti fi lélẹ̀, mo sì ní àṣẹ láti tún un gbà.+ Ọwọ́ Baba mi ni mo ti gba àṣẹ yìí.”