-
Ìṣe 15:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Nítorí náà, à ń rán Júdásì àti Sílà bọ̀, kí àwọn náà lè fi ọ̀rọ̀ ẹnu jíṣẹ́ + ohun kan náà fún yín.
-
-
Ìṣe 17:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, àwọn ará ní kí Pọ́ọ̀lù máa lọ sí etí òkun,+ àmọ́ Sílà àti Tímótì dúró síbẹ̀.
-