1 Kọ́ríńtì 16:8, 9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àmọ́ màá wà ní Éfésù+ títí di ìgbà Àjọyọ̀ Pẹ́ńtíkọ́sì, 9 nítorí ilẹ̀kùn ńlá ti ṣí sílẹ̀ fún mi láti ṣe iṣẹ́ púpọ̀,+ àmọ́ ọ̀pọ̀ alátakò ló wà.
8 Àmọ́ màá wà ní Éfésù+ títí di ìgbà Àjọyọ̀ Pẹ́ńtíkọ́sì, 9 nítorí ilẹ̀kùn ńlá ti ṣí sílẹ̀ fún mi láti ṣe iṣẹ́ púpọ̀,+ àmọ́ ọ̀pọ̀ alátakò ló wà.