Ìṣe 1:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Lẹ́yìn tó ti jìyà, ó fara hàn wọ́n láàyè nípasẹ̀ ọ̀pọ̀ ẹ̀rí tó dájú.+ Wọ́n rí i jálẹ̀ ogójì (40) ọjọ́, ó sì ń sọ̀rọ̀ nípa Ìjọba Ọlọ́run.+ Ìṣe 28:30, 31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Torí náà, ó lo odindi ọdún méjì ní ilé tí òun fúnra rẹ̀ gbà,+ ó sì máa ń gba gbogbo àwọn tó bá wá sọ́dọ̀ rẹ̀ tọwọ́tẹsẹ̀, 31 ó ń wàásù Ìjọba Ọlọ́run fún wọn, ó sì ń kọ́ wọn nípa Jésù Kristi Olúwa ní fàlàlà,*+ láìsí ìdíwọ́.
3 Lẹ́yìn tó ti jìyà, ó fara hàn wọ́n láàyè nípasẹ̀ ọ̀pọ̀ ẹ̀rí tó dájú.+ Wọ́n rí i jálẹ̀ ogójì (40) ọjọ́, ó sì ń sọ̀rọ̀ nípa Ìjọba Ọlọ́run.+
30 Torí náà, ó lo odindi ọdún méjì ní ilé tí òun fúnra rẹ̀ gbà,+ ó sì máa ń gba gbogbo àwọn tó bá wá sọ́dọ̀ rẹ̀ tọwọ́tẹsẹ̀, 31 ó ń wàásù Ìjọba Ọlọ́run fún wọn, ó sì ń kọ́ wọn nípa Jésù Kristi Olúwa ní fàlàlà,*+ láìsí ìdíwọ́.