Ìṣe 20:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ní báyìí, ẹ wò ó! ẹ̀mí ti sọ ọ́ di dandan fún mi,* mò ń rin ìrìn àjò lọ sí Jerúsálẹ́mù, bó tilẹ̀ jẹ́ pé mi ò mọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí mi níbẹ̀,
22 Ní báyìí, ẹ wò ó! ẹ̀mí ti sọ ọ́ di dandan fún mi,* mò ń rin ìrìn àjò lọ sí Jerúsálẹ́mù, bó tilẹ̀ jẹ́ pé mi ò mọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí mi níbẹ̀,