Ìṣe 23:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àmọ́ ní òru ọjọ́ náà, Olúwa dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀, ó sì sọ pé: “Mọ́kàn le!+ Nítorí pé bí o ṣe ń jẹ́rìí kúnnákúnná nípa mi ní Jerúsálẹ́mù, bẹ́ẹ̀ lo ṣe máa jẹ́rìí ní Róòmù.”+
11 Àmọ́ ní òru ọjọ́ náà, Olúwa dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀, ó sì sọ pé: “Mọ́kàn le!+ Nítorí pé bí o ṣe ń jẹ́rìí kúnnákúnná nípa mi ní Jerúsálẹ́mù, bẹ́ẹ̀ lo ṣe máa jẹ́rìí ní Róòmù.”+