2 Tímótì 4:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Érásítù+ dúró sí Kọ́ríńtì, àmọ́ mo fi Tírófímù+ sílẹ̀ ní Mílétù, ara rẹ̀ ò yá.