Éfésù 6:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Kí ẹ lè mọ̀ nípa mi àti bí mo ṣe ń ṣe sí, Tíkíkù,+ arákùnrin ọ̀wọ́n, tó tún jẹ́ òjíṣẹ́ olóòótọ́ nínú Olúwa, yóò sọ gbogbo rẹ̀ fún yín.+ Kólósè 4:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Tíkíkù,+ arákùnrin mi ọ̀wọ́n tó jẹ́ òjíṣẹ́ olóòótọ́ àti ẹrú ẹlẹgbẹ́ mi nínú Olúwa, máa ròyìn gbogbo ohun tó ṣẹlẹ̀ sí mi fún yín. 2 Tímótì 4:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àmọ́ mo ti rán Tíkíkù+ lọ sí Éfésù.
21 Kí ẹ lè mọ̀ nípa mi àti bí mo ṣe ń ṣe sí, Tíkíkù,+ arákùnrin ọ̀wọ́n, tó tún jẹ́ òjíṣẹ́ olóòótọ́ nínú Olúwa, yóò sọ gbogbo rẹ̀ fún yín.+
7 Tíkíkù,+ arákùnrin mi ọ̀wọ́n tó jẹ́ òjíṣẹ́ olóòótọ́ àti ẹrú ẹlẹgbẹ́ mi nínú Olúwa, máa ròyìn gbogbo ohun tó ṣẹlẹ̀ sí mi fún yín.