Máàkù 1:14, 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Lẹ́yìn tí wọ́n mú Jòhánù, Jésù lọ sí Gálílì,+ ó ń wàásù ìhìn rere Ọlọ́run,+ 15 ó ń sọ pé: “Àkókò tí a yàn ti pé, Ìjọba Ọlọ́run sì ti sún mọ́lé. Ẹ ronú pìwà dà,+ kí ẹ sì ní ìgbàgbọ́ nínú ìhìn rere.”
14 Lẹ́yìn tí wọ́n mú Jòhánù, Jésù lọ sí Gálílì,+ ó ń wàásù ìhìn rere Ọlọ́run,+ 15 ó ń sọ pé: “Àkókò tí a yàn ti pé, Ìjọba Ọlọ́run sì ti sún mọ́lé. Ẹ ronú pìwà dà,+ kí ẹ sì ní ìgbàgbọ́ nínú ìhìn rere.”