1 Tímótì 4:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Máa kíyè sí ara rẹ àti ẹ̀kọ́ rẹ+ nígbà gbogbo. Rí i pé o ò jáwọ́ nínú ṣíṣe àwọn nǹkan yìí, torí tí o bá ń ṣe é, wàá lè gba ara rẹ àti àwọn tó ń fetí sí ọ là.+
16 Máa kíyè sí ara rẹ àti ẹ̀kọ́ rẹ+ nígbà gbogbo. Rí i pé o ò jáwọ́ nínú ṣíṣe àwọn nǹkan yìí, torí tí o bá ń ṣe é, wàá lè gba ara rẹ àti àwọn tó ń fetí sí ọ là.+