Mátíù 28:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Jésù sún mọ́ wọn, ó sì sọ fún wọn pé: “Gbogbo àṣẹ ní ọ̀run àti ayé la ti fún mi.+ Jòhánù 3:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Baba nífẹ̀ẹ́ Ọmọ,+ ó sì ti fi gbogbo nǹkan sí ìkáwọ́ rẹ̀.+ Ìṣe 5:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ọlọ́run gbé ẹni yìí ga sí ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀+ láti jẹ́ Olórí Aṣojú+ àti Olùgbàlà,+ kí ó lè mú kí Ísírẹ́lì ronú pìwà dà, kí wọ́n sì rí ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ gbà.+
31 Ọlọ́run gbé ẹni yìí ga sí ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀+ láti jẹ́ Olórí Aṣojú+ àti Olùgbàlà,+ kí ó lè mú kí Ísírẹ́lì ronú pìwà dà, kí wọ́n sì rí ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ gbà.+