Ìṣe 11:27, 28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ní àkókò yẹn, àwọn wòlíì+ wá láti Jerúsálẹ́mù sí Áńtíókù. 28 Ọ̀kan lára wọn tó ń jẹ́ Ágábù + dìde, ó sì sọ tẹ́lẹ̀ nípasẹ̀ ẹ̀mí pé ìyàn ńlá máa tó mú ní gbogbo ilẹ̀ ayé+ tí à ń gbé, èyí sì ṣẹlẹ̀ lóòótọ́ lásìkò Kíláúdíù.
27 Ní àkókò yẹn, àwọn wòlíì+ wá láti Jerúsálẹ́mù sí Áńtíókù. 28 Ọ̀kan lára wọn tó ń jẹ́ Ágábù + dìde, ó sì sọ tẹ́lẹ̀ nípasẹ̀ ẹ̀mí pé ìyàn ńlá máa tó mú ní gbogbo ilẹ̀ ayé+ tí à ń gbé, èyí sì ṣẹlẹ̀ lóòótọ́ lásìkò Kíláúdíù.