Ìṣe 4:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nígbà tí àwọn méjèèjì ń bá àwọn èèyàn sọ̀rọ̀ lọ́wọ́, àwọn àlùfáà, olórí ẹ̀ṣọ́ tẹ́ńpìlì àti àwọn Sadusí+ wá bá wọn. 2 Inú ń bí wọn torí pé àwọn àpọ́sítélì ń kọ́ àwọn èèyàn, wọ́n sì ń kéde ní gbangba nípa àjíǹde Jésù kúrò nínú ikú.*+
4 Nígbà tí àwọn méjèèjì ń bá àwọn èèyàn sọ̀rọ̀ lọ́wọ́, àwọn àlùfáà, olórí ẹ̀ṣọ́ tẹ́ńpìlì àti àwọn Sadusí+ wá bá wọn. 2 Inú ń bí wọn torí pé àwọn àpọ́sítélì ń kọ́ àwọn èèyàn, wọ́n sì ń kéde ní gbangba nípa àjíǹde Jésù kúrò nínú ikú.*+