-
Ìṣe 21:27, 28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Nígbà tó kù díẹ̀ kí ọjọ́ méje náà pé, àwọn Júù tó wá láti Éṣíà rí i nínú tẹ́ńpìlì, ni wọ́n bá ru gbogbo èrò lọ́kàn sókè, wọ́n sì gbá a mú, 28 wọ́n ń kígbe pé: “Ẹ̀yin èèyàn Ísírẹ́lì, ẹ gbà wá o! Ọkùnrin tó ń kọ́ gbogbo èèyàn níbi gbogbo láti kẹ̀yìn sí àwọn èèyàn wa àti sí Òfin àti sí ibí yìí ti dé síbí o. Yàtọ̀ síyẹn, ó tún mú àwọn Gíríìkì wá sínú tẹ́ńpìlì, ó sì ti sọ ibi mímọ́ yìí di ẹlẹ́gbin.”+
-