-
Ìṣe 21:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Nígbà tí a dé Jerúsálẹ́mù, àwọn ará gbà wá tayọ̀tayọ̀.
-
-
Ìṣe 21:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Lẹ́yìn náà, Pọ́ọ̀lù mú àwọn ọkùnrin náà dání ní ọjọ́ kejì, ó sì wẹ ara rẹ̀ mọ́ pẹ̀lú wọn lọ́nà Òfin,+ ó wọ tẹ́ńpìlì lọ láti sọ ìgbà tí àwọn ọjọ́ ìwẹ̀mọ́ náà máa parí, kí àlùfáà lè rú ẹbọ fún ẹnì kọ̀ọ̀kan wọn.
-