Ìṣe 25:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Àmọ́ mo fún wọn lésì pé kò bá ìlànà àwọn ara Róòmù mu pé kí a fi ẹnì kan léni lọ́wọ́ láti fi wá ojú rere, kí ẹni tí wọ́n fẹ̀sùn kàn náà tó fojú kojú pẹ̀lú àwọn tó fẹ̀sùn kàn án, kí ó sì láǹfààní láti gbèjà ara rẹ̀ lórí ẹ̀sùn náà.+
16 Àmọ́ mo fún wọn lésì pé kò bá ìlànà àwọn ara Róòmù mu pé kí a fi ẹnì kan léni lọ́wọ́ láti fi wá ojú rere, kí ẹni tí wọ́n fẹ̀sùn kàn náà tó fojú kojú pẹ̀lú àwọn tó fẹ̀sùn kàn án, kí ó sì láǹfààní láti gbèjà ara rẹ̀ lórí ẹ̀sùn náà.+