-
Ìṣe 2:46Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
46 Láti ọjọ́ dé ọjọ́, wọ́n ń pésẹ̀ déédéé sí tẹ́ńpìlì pẹ̀lú èrò tó ṣọ̀kan, wọ́n ń jẹun ní ilé ara wọn, wọ́n sì ń fi ayọ̀ púpọ̀ àti òótọ́ ọkàn pín oúnjẹ fún ara wọn,
-