-
Ìṣe 25:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Nígbà tó wọlé, àwọn Júù tó wá láti Jerúsálẹ́mù dúró yí i ká, wọ́n ń fi ọ̀pọ̀ ẹ̀sùn tó lágbára kàn án, àwọn ẹ̀sùn tí wọn kò lè fi ẹ̀rí rẹ̀ hàn.+
-