Ìṣe 25:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Fẹ́sítọ́ọ̀sì, tó ń wá ojú rere àwọn Júù,+ dá Pọ́ọ̀lù lóhùn pé: “Ṣé o fẹ́ lọ sí Jerúsálẹ́mù, kí a lè dá ẹjọ́ rẹ níbẹ̀ níwájú mi lórí àwọn nǹkan yìí?”
9 Fẹ́sítọ́ọ̀sì, tó ń wá ojú rere àwọn Júù,+ dá Pọ́ọ̀lù lóhùn pé: “Ṣé o fẹ́ lọ sí Jerúsálẹ́mù, kí a lè dá ẹjọ́ rẹ níbẹ̀ níwájú mi lórí àwọn nǹkan yìí?”