ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìṣe 25:11, 12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Tó bá jẹ́ pé oníwà àìtọ́ ni mí lóòótọ́, tí mo sì ti ṣe ohun tó yẹ fún ikú,+ mi ò bẹ̀bẹ̀ pé kí ẹ má pa mí; àmọ́ tí kò bá sí òótọ́ nínú gbogbo ẹ̀sùn tí àwọn ọkùnrin yìí fi kàn mí, kò sẹ́ni tó lẹ́tọ̀ọ́ láti fi mí lé wọn lọ́wọ́ kó lè fi wá ojú rere. Mo ké gbàjarè sí Késárì!”+ 12 Lẹ́yìn tí Fẹ́sítọ́ọ̀sì ti bá àwùjọ àwọn agbani-nímọ̀ràn sọ̀rọ̀, ó fèsì pé: “Késárì lo ké gbàjarè sí; ọ̀dọ̀ Késárì ni wàá sì lọ.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́