Jòhánù 8:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 12 Jésù tún sọ fún wọn pé: “Èmi ni ìmọ́lẹ̀ ayé.+ Ó dájú pé ẹnikẹ́ni tó bá ń tẹ̀ lé mi kò ní rìn nínú òkùnkùn, àmọ́ ó máa ní ìmọ́lẹ̀+ ìyè.” 2 Kọ́ríńtì 4:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Torí Ọlọ́run ni ẹni tó sọ pé: “Kí ìmọ́lẹ̀ tàn láti inú òkùnkùn,”+ ó sì ti tan ìmọ́lẹ̀ sí ọkàn wa+ láti mú kí ìmọ̀ ológo nípa Ọlọ́run mọ́lẹ̀ nípasẹ̀ ojú Kristi.
8 12 Jésù tún sọ fún wọn pé: “Èmi ni ìmọ́lẹ̀ ayé.+ Ó dájú pé ẹnikẹ́ni tó bá ń tẹ̀ lé mi kò ní rìn nínú òkùnkùn, àmọ́ ó máa ní ìmọ́lẹ̀+ ìyè.”
6 Torí Ọlọ́run ni ẹni tó sọ pé: “Kí ìmọ́lẹ̀ tàn láti inú òkùnkùn,”+ ó sì ti tan ìmọ́lẹ̀ sí ọkàn wa+ láti mú kí ìmọ̀ ológo nípa Ọlọ́run mọ́lẹ̀ nípasẹ̀ ojú Kristi.