Mátíù 19:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Jésù sọ fún un pé: “Tí o bá fẹ́ jẹ́ pípé,* lọ ta àwọn ohun ìní rẹ, kí o fún àwọn aláìní, wàá sì ní ìṣúra ní ọ̀run;+ kí o wá máa tẹ̀ lé mi.”+
21 Jésù sọ fún un pé: “Tí o bá fẹ́ jẹ́ pípé,* lọ ta àwọn ohun ìní rẹ, kí o fún àwọn aláìní, wàá sì ní ìṣúra ní ọ̀run;+ kí o wá máa tẹ̀ lé mi.”+