-
Ìṣe 25:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Lẹ́yìn tí Fẹ́sítọ́ọ̀sì ti bá àwùjọ àwọn agbani-nímọ̀ràn sọ̀rọ̀, ó fèsì pé: “Késárì lo ké gbàjarè sí; ọ̀dọ̀ Késárì ni wàá sì lọ.”