Ìṣe 24:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Nígbà tí gómìnà mi orí sí Pọ́ọ̀lù pé kó sọ̀rọ̀, ó fèsì pé: “Bí mo ṣe mọ̀ dáadáa pé ọ̀pọ̀ ọdún lo ti ń ṣe onídàájọ́ orílẹ̀-èdè yìí, mo ṣe tán láti gbèjà ara mi.+
10 Nígbà tí gómìnà mi orí sí Pọ́ọ̀lù pé kó sọ̀rọ̀, ó fèsì pé: “Bí mo ṣe mọ̀ dáadáa pé ọ̀pọ̀ ọdún lo ti ń ṣe onídàájọ́ orílẹ̀-èdè yìí, mo ṣe tán láti gbèjà ara mi.+