Ìṣe 5:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Ọlọ́run àwọn baba ńlá wa gbé Jésù dìde, ẹni tí ẹ pa, tí ẹ sì gbé kọ́ òpó igi.*+