Dáníẹ́lì 2:20, 21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Dáníẹ́lì sọ pé: “Ẹ yin orúkọ Ọlọ́run títí ayé,*Torí òun nìkan ló ni ọgbọ́n àti agbára.+ 21 Ó ń yí ìgbà àti àsìkò pa dà,+Ó ń mú ọba kúrò, ó sì ń fi ọba jẹ,+Ó ń fún àwọn ọlọ́gbọ́n ní ọgbọ́n, ó sì ń fún àwọn tó ní òye ní ìmọ̀.+ Mátíù 24:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 “Ní ti ọjọ́ àti wákàtí yẹn, kò sí ẹni tó mọ̀ ọ́n,+ àwọn áńgẹ́lì ọ̀run àti Ọmọ pàápàá kò mọ̀ ọ́n, àfi Baba nìkan.+
20 Dáníẹ́lì sọ pé: “Ẹ yin orúkọ Ọlọ́run títí ayé,*Torí òun nìkan ló ni ọgbọ́n àti agbára.+ 21 Ó ń yí ìgbà àti àsìkò pa dà,+Ó ń mú ọba kúrò, ó sì ń fi ọba jẹ,+Ó ń fún àwọn ọlọ́gbọ́n ní ọgbọ́n, ó sì ń fún àwọn tó ní òye ní ìmọ̀.+
36 “Ní ti ọjọ́ àti wákàtí yẹn, kò sí ẹni tó mọ̀ ọ́n,+ àwọn áńgẹ́lì ọ̀run àti Ọmọ pàápàá kò mọ̀ ọ́n, àfi Baba nìkan.+