1 Kọ́ríńtì 1:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Ṣùgbọ́n òun ló mú kí ẹ wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Kristi Jésù, ẹni tó fi ọgbọ́n Ọlọ́run àti òdodo rẹ̀+ hàn wá, ó sọ wá di mímọ́,+ ó sì tú wa sílẹ̀ nípasẹ̀ ìràpadà,+ 1 Jòhánù 1:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Tí a bá jẹ́wọ́ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa, ó máa dárí jì wá, ó sì máa wẹ̀ wá mọ́ kúrò nínú gbogbo àìṣòdodo torí olóòótọ́ àti olódodo ni.+
30 Ṣùgbọ́n òun ló mú kí ẹ wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Kristi Jésù, ẹni tó fi ọgbọ́n Ọlọ́run àti òdodo rẹ̀+ hàn wá, ó sọ wá di mímọ́,+ ó sì tú wa sílẹ̀ nípasẹ̀ ìràpadà,+
9 Tí a bá jẹ́wọ́ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa, ó máa dárí jì wá, ó sì máa wẹ̀ wá mọ́ kúrò nínú gbogbo àìṣòdodo torí olóòótọ́ àti olódodo ni.+