Róòmù 3:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Nítorí ọ̀kan ni Ọlọ́run,+ ó máa pe àwọn tó dádọ̀dọ́* ní olódodo + nítorí ìgbàgbọ́, á sì pe àwọn aláìdádọ̀dọ́* ní olódodo + nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ wọn.
30 Nítorí ọ̀kan ni Ọlọ́run,+ ó máa pe àwọn tó dádọ̀dọ́* ní olódodo + nítorí ìgbàgbọ́, á sì pe àwọn aláìdádọ̀dọ́* ní olódodo + nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ wọn.