Róòmù 4:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Kí ni ìwé mímọ́ sọ? “Ábúráhámù ní ìgbàgbọ́ nínú Jèhófà,* ó sì kà á sí òdodo fún un.”+