Gálátíà 3:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Yàtọ̀ síyẹn, bí ẹ bá jẹ́ ti Kristi, ẹ jẹ́ ọmọ* Ábúráhámù lóòótọ́,+ ajogún+ nípasẹ̀ ìlérí.+