Róòmù 3:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 bí a ṣe pè wọ́n ní olódodo dà bí ẹ̀bùn ọ̀fẹ́+ tí wọ́n rí gbà nípasẹ̀ inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí rẹ̀,+ èyí tó wá nípasẹ̀ ìtúsílẹ̀ tí ìràpadà tí Kristi Jésù san mú kó ṣeé ṣe.+
24 bí a ṣe pè wọ́n ní olódodo dà bí ẹ̀bùn ọ̀fẹ́+ tí wọ́n rí gbà nípasẹ̀ inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí rẹ̀,+ èyí tó wá nípasẹ̀ ìtúsílẹ̀ tí ìràpadà tí Kristi Jésù san mú kó ṣeé ṣe.+