Róòmù 4:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ó gba àmì kan,+ ìyẹn, ìdádọ̀dọ́,* gẹ́gẹ́ bí èdìdì* òdodo nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ tó ní nígbà tó ṣì jẹ́ aláìdádọ̀dọ́,* kí ó lè jẹ́ baba gbogbo àwọn tó ní ìgbàgbọ́+ nígbà tí wọ́n ṣì jẹ́ aláìdádọ̀dọ́, kí a lè kà wọ́n sí olódodo;
11 Ó gba àmì kan,+ ìyẹn, ìdádọ̀dọ́,* gẹ́gẹ́ bí èdìdì* òdodo nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ tó ní nígbà tó ṣì jẹ́ aláìdádọ̀dọ́,* kí ó lè jẹ́ baba gbogbo àwọn tó ní ìgbàgbọ́+ nígbà tí wọ́n ṣì jẹ́ aláìdádọ̀dọ́, kí a lè kà wọ́n sí olódodo;