Jẹ́nẹ́sísì 17:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ni Ábúráhámù bá dojú bolẹ̀, ó bẹ̀rẹ̀ sí í rẹ́rìn-ín, ó sì ń sọ lọ́kàn rẹ̀+ pé: “Ṣé ọkùnrin ẹni ọgọ́rùn-ún (100) ọdún lè di bàbá ọmọ? Ṣé Sérà, obìnrin ẹni àádọ́rùn-ún (90) ọdún sì lè bímọ?”+
17 Ni Ábúráhámù bá dojú bolẹ̀, ó bẹ̀rẹ̀ sí í rẹ́rìn-ín, ó sì ń sọ lọ́kàn rẹ̀+ pé: “Ṣé ọkùnrin ẹni ọgọ́rùn-ún (100) ọdún lè di bàbá ọmọ? Ṣé Sérà, obìnrin ẹni àádọ́rùn-ún (90) ọdún sì lè bímọ?”+