Hébérù 11:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Àmọ́, ó ronú pé Ọlọ́run lè gbé e dìde tó bá tiẹ̀ kú, ó sì rí i gbà láti ibẹ̀ lọ́nà àpèjúwe.+