Jòhánù 3:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Ẹni tó bá ń ní ìgbàgbọ́ nínú Ọmọ ní ìyè àìnípẹ̀kun;+ ẹni tó bá ń ṣàìgbọràn sí Ọmọ kò ní rí ìyè,+ àmọ́ ìbínú Ọlọ́run wà lórí rẹ̀.+ Róòmù 3:21, 22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Àmọ́ ní báyìí, láìgbára lé òfin, a ti fi òdodo Ọlọ́run hàn,+ bí Òfin àti àwọn Wòlíì ṣe jẹ́rìí sí i,+ 22 bẹ́ẹ̀ ni, òdodo Ọlọ́run nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ nínú Jésù Kristi, tó wà fún gbogbo àwọn tó ní ìgbàgbọ́. Nítorí kò sí ìyàtọ̀.+
36 Ẹni tó bá ń ní ìgbàgbọ́ nínú Ọmọ ní ìyè àìnípẹ̀kun;+ ẹni tó bá ń ṣàìgbọràn sí Ọmọ kò ní rí ìyè,+ àmọ́ ìbínú Ọlọ́run wà lórí rẹ̀.+
21 Àmọ́ ní báyìí, láìgbára lé òfin, a ti fi òdodo Ọlọ́run hàn,+ bí Òfin àti àwọn Wòlíì ṣe jẹ́rìí sí i,+ 22 bẹ́ẹ̀ ni, òdodo Ọlọ́run nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ nínú Jésù Kristi, tó wà fún gbogbo àwọn tó ní ìgbàgbọ́. Nítorí kò sí ìyàtọ̀.+