-
Róòmù 2:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Àmọ́ nítorí agídí rẹ àti ọkàn rẹ tí kò ronú pìwà dà, ò ń kó ìrunú jọ sórí ara rẹ, ìrunú yìí máa hàn ní ọjọ́ ìdájọ́ òdodo Ọlọ́run.+
-
-
Éfésù 5:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ẹ má ṣe jẹ́ kí èèyàn kankan fi ọ̀rọ̀ asán tàn yín jẹ, ìdí ni pé torí irú àwọn nǹkan yìí ni ìrunú Ọlọ́run ṣe ń bọ̀ lórí àwọn ọmọ aláìgbọràn.
-