Róòmù 5:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ìdí nìyẹn tó fi jẹ́ pé, bí ẹ̀ṣẹ̀ ṣe tipasẹ̀ ẹnì kan wọ ayé, tí ikú sì wá nípasẹ̀ ẹ̀ṣẹ̀,+ bẹ́ẹ̀ ni ikú ṣe tàn dé ọ̀dọ̀ gbogbo èèyàn torí pé gbogbo wọn ti dẹ́ṣẹ̀+—. Róòmù 5:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Síbẹ̀, ikú jọba láti ọ̀dọ̀ Ádámù títí dé ọ̀dọ̀ Mósè, àní lórí àwọn tí kò dẹ́ṣẹ̀ bíi ti Ádámù, ẹni tó fara jọ ẹni tó ń bọ̀.+
12 Ìdí nìyẹn tó fi jẹ́ pé, bí ẹ̀ṣẹ̀ ṣe tipasẹ̀ ẹnì kan wọ ayé, tí ikú sì wá nípasẹ̀ ẹ̀ṣẹ̀,+ bẹ́ẹ̀ ni ikú ṣe tàn dé ọ̀dọ̀ gbogbo èèyàn torí pé gbogbo wọn ti dẹ́ṣẹ̀+—.
14 Síbẹ̀, ikú jọba láti ọ̀dọ̀ Ádámù títí dé ọ̀dọ̀ Mósè, àní lórí àwọn tí kò dẹ́ṣẹ̀ bíi ti Ádámù, ẹni tó fara jọ ẹni tó ń bọ̀.+