Róòmù 3:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Nítorí náà, kò sí ẹni* tí a máa pè ní olódodo níwájú rẹ̀ nípasẹ̀ àwọn iṣẹ́ òfin,+ torí òfin ló jẹ́ ká ní ìmọ̀ pípéye nípa ẹ̀ṣẹ̀.+ Gálátíà 3:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ti Òfin ti wá jẹ́? A fi kún un láti mú kí àwọn àṣìṣe fara hàn kedere,+ títí ọmọ* tí a ṣe ìlérí náà fún á fi dé;+ a sì fi í rán àwọn áńgẹ́lì + nípasẹ̀ alárinà kan.+
20 Nítorí náà, kò sí ẹni* tí a máa pè ní olódodo níwájú rẹ̀ nípasẹ̀ àwọn iṣẹ́ òfin,+ torí òfin ló jẹ́ ká ní ìmọ̀ pípéye nípa ẹ̀ṣẹ̀.+
19 Ti Òfin ti wá jẹ́? A fi kún un láti mú kí àwọn àṣìṣe fara hàn kedere,+ títí ọmọ* tí a ṣe ìlérí náà fún á fi dé;+ a sì fi í rán àwọn áńgẹ́lì + nípasẹ̀ alárinà kan.+