-
1 Tímótì 1:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Síbẹ̀, a fi àánú hàn sí mi, kó lè jẹ́ pé nípasẹ̀ èmi tí mo jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ nínú ẹlẹ́ṣẹ̀, Kristi Jésù máa fi gbogbo sùúrù rẹ̀ hàn, kó lè fi mí ṣe àpẹẹrẹ fún àwọn tó máa gbà á gbọ́ kí wọ́n lè ní ìyè àìnípẹ̀kun.+
-